Wednesday, January 20, 2010

IJOBA ORUN BY LARA GEORGE

Ijoba orun
by Lara George


Uhhhuhhhh
Uhuh

Ijoba orun
Ere Onigbagbo o
Ijoba orun
Ere Onigbagbo o

Ma je n kuna
Baba
Mu mi dele o
Ma je n kuna
Baba se
Mu mi dele o

Owo ti mo ni
ko le mu mi dele o
Moto ti mo ri ra
ko le wa mi dele o
Ore ti mo ni
ko le sinmi dele o
Gbogbo iwe ti mo ri ka
won o le gbe mi dele oMa je n kuna
Baba
Mu mi dele o
ki n ma ku sajo bi efin
Mu mi dele o
Aye loja, oorun ni ile
Mu mi dele o
Aye loja yi, oorun nile se
Mu mi dele o

Mu mi dele o (x8)
Ma ma je n kuna
Baba ooo
Baba ooo
Mu mi dele o (x5)

Ile ogo
Ile ayo, Ile ayo
Ile alafia
Ile ogo
Ile ayo, Ile ayo
Ile alafia

Ijoba orun
Ere onigbagbo o
Ijoba oorun
Ere onigbagbo o
Ma je n kuna

No comments:

Post a Comment